Ìkéde Nípa Ìpàdé Àwọn Olùkópa Ọjà Ìdókòwò Tí a tẹ̀ jáde: July 18, 2018
À ń sọ fún gbogbo ènìyàn àti àwọn tó ní ipa nínú ọjà ìdókòwò pé a ti sun Ìpàdé 2 ti Àwọn Olùkópa Ọjà Ìdókòwò, tí National Assembly Committee on Capital Market, Securities & Exchange Commission àti àwọn olùkópa míì ń ṣètò, kúrò ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun, 17, 2018 sí Ọjọ́ Ajé, 23 Oṣù Keje 2018.
Ibi àti àkókò ìpàdé kò yí padà.